BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
A ti ń ṣiṣẹ́ láti gba ìtúsílẹ̀ àwọn àgùnbánirọ̀ tí wọ́n jí gbé ní ìpínlẹ̀ Imo - Ìjọba Oyo
Awọn ibudo ifinimọle awọn agunbanirọ to wa ni ipinlẹ Imo ati Akwa Ibom ni awọn bọọsi naa n ko awọn eeyan naa lọ ki wọn to ji wọn gbe ni Ọjọbọ.
Ẹ jẹ́ kí n padà sí sinimá ṣiṣe, ó hàn pé mí ò kí ń ṣe ẹlẹ́ṣẹ́ – Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n jàn án mọ́lẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀ṣẹ́
Ija naa ni akọkọ iru rẹ fun awọn gbajumọ obinrin ni Naijiria, eyii ti ileeṣẹ Balmoral Promotions ṣe agbatẹru rẹ.
Olu Jacobs, àgbà òṣèré wọ káà ilẹ̀ sún l'Ekoo
Ọjọ́ Ẹti, ọjọ́ kejì oṣù Kẹwàá ọdún 2026 yìí ni wọn sìnkú Olú Jacobs si itẹ òkú Ikoyi, niluu Eko.
Kà nípa kòkúmọ́ obìnrin tí wọ́n gún lábẹ́rẹ́ ikú nígbà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ àmọ́ tí kò kú
Ikọ agbẹjọro Christa Pike, niluu Tennessee pe ẹjọ pajawiri pe ki wọn da iku rẹ duro lasiko ti wọn n gbiyanju lati gbẹmi rẹ lọwọ pe ọdaran ọhun ti daku bo tilẹ jẹ pe o ṣi n mi, to si n hanrun.
Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 1,02
Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri àgbáyé tí kò ṣe è má gbọ̀ ọ́
Fídíò, Gbájúẹ̀ oúnjẹ olówópọ́ọ́kú dá wàhálà sílẹ̀ l'Osun, àwọn kan ní àwọn yóò tún tẹ́rí síi lọ́jọ́ ìwájú, àwọn yóò tún tẹ́rí síi
A gbọ pe ileeṣẹ naa sọ fun awọn eeyan naa pe awọn wọ ilu lati ran wọn lọwọ lori ọrọ ounjẹ bii irẹsi, ororo, sẹmo ati bẹẹbẹẹ lọ.
Àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ kéde ìyanṣẹ́lódì oníkìlọ̀ ọlọ́jọ́ mẹ́ta
JNPSNC lo jẹ apapọ ẹgbẹ oṣiṣẹ NLC, TUC atawọn ẹgbẹ oṣiṣẹ mii, ti wọn si maa n panupọ lati fi beere ẹtọ wọn lọwọ ijọba apapọ.
Wo àwọn èèkàn méje tó ṣe agbátẹrù bí Nàìjíríà ṣe gba òmìnira lọ́dùn 1960
Ọjọ Kiini, oṣu Kewaa, ọdun 1960 ni Naijiria ja ogun ajabọ lọwọ ijọba ilẹ Gẹẹsi ṣugbọn aṣeyọri naa ko ṣẹyin awọn ọmọ Naijiria kan ti wọn ja fitafita lati gba ominira naa.
Fídíò, Bí mo bá rántí bí Nàìjíríà ṣe bẹ̀rẹ̀, ó máa ń dùnmí gán ní, àìní sùúrú kóbá wa – Yemi Farombi, Duration 4,14
Alagba Yẹmi Farounbi ṣalaye pe eyi ti ologun da silẹ lara ohun to n ṣe Naijiria pọ pupọ.
Ńjẹ́ o mọ̀ pé àdó olóró ti bú rí nítòsí ààrẹ lásìkò àyàjọ́ òmìnira ní Nàìjíríà? Ohun mánigbàgbé márun tó wáyé rí lọ́jọ́ àyájọ́ òmìnira
Ọmọọbabinrin Alexandra ti Kent lo ṣoju Ọbabinrin Elizabeth keji nibi ayẹyẹ ọhun, o si ti de si Naijiria lati ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu Kẹsa, ọdun naa.
Wo kókó ohun tí Ààrẹ Tinubu bá àwọn ọmọ Naijiria sọ ní àyájọ́ òmìnira
Tinubu sọ pe Naijiria ti n wọ igba ọtun ninu eyii ti ipese iṣẹ, idagbasoke awọn ileesẹẹ ati mimu adinkuba oṣi wa.
Fídíò, 'Mo fẹ́ bá àwọn tí kò bọ̀wọ̀ fún mi wí láì lo ẹgba' Gbajúmọ̀ òṣèré', Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ ṣáàjú ẹ̀ṣẹ̀ kíkàn tó fẹ́ jà pẹ̀lú Phyna, Duration 1,17
Aṣalẹ Ọjọbọ ni ija ẹṣẹ kikan naa yoo waye.
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
Ta ló ni agbárí èèyàn 28 tí ọlọ́pàá rí nínú aginjù, èyí tó ń dá awuyewuye sílẹ̀ báyìí?
Awọn to n ṣe iwadii iṣẹlẹ naa n sọ pe o ṣeeṣe ki awọn egungun agbari naa jẹ ti awọn eeyan ti wọn ji gbe lagbegbe naa.
Ṣé lóòótọ́ ni Ààrẹ Naijiria lè máa ṣèjọba láti ilẹ̀ òkèrè?
Ọpọ eeyan lo n bu ẹnu atẹ lu Tinubu lori bo ṣe lọ isinimi naa lai gbe ijọba kalẹ fun igbakeji rẹ, Kashim Shettima.
Wo ohun tí a mọ̀ nípa àwọn afúrásí tí wọ́n nawọ́ gán ní ibùdó RAF Fairford ní UK
Ileeṣẹ ọlọpaa Gloucestershire sọ pe awọn gba ipe ni oru ọjọ Aiku pe awọn ọkọ meta kan n rin lọna RAF Fairford ti irinajo si mu ifura lọwọ.
Ọ̀kan ṣoṣo tó kù nínú gbogbo nǹkan tí mo fẹ́ ṣe nílé ayé rèé – Fatomilola
Ilumọọka oṣere naa sọ pe nnkan ẹyọkan yii ni oun le sọ pe Ọba Oke ko tii fontẹ lu.
Ó dèèwọ̀! Ẹgbẹ́ òṣèlú APC fòfin de àwọn olùdíje pé wọn ò gbọdọ̀ rin ìrìn àjò lọ sókè òkun lásìkò ètò ìdìbò
Cornelius Ojelabi to jẹ alaga ẹgbẹ oṣelu naa lo sọrọ naa laipẹ yii lasiko to n ṣe ifilọlẹ igbimọ iṣakoso fun eto idibo PBAT/KOH nile ẹgbẹ naa to wa lagbegbe Ikeja.
Èèyàn 27 jáde láyé bí àwọn agbébọn ṣe kọlu ilé ìgbáfẹ́ méjì mọ́júmọ́
Ileeṣẹ ọlọpaa orilẹ ede naa ṣalaye pe nnkan bii aago mẹsan-an abọ alẹ ọjọ Abamẹta ni awọn agbebọn kan yawọ ile igbafẹ ni Carletonville, ti ko ju ọgọrin kilomita si Johannesburg lọ ti wọn si gbẹmi eeyan mẹtadinlogun (17).
Ta ni Omowunmi Dada, gbajúmọ̀ òṣèré tí sinimá òun àti Lateef Adedimeji, Itele D Icon, gba àmì ẹ̀yẹ GWR?
Gẹge bi ileeṣẹ Guiness World Record ṣe sọ, ẹgbẹrun mọkanlelaaadọta eeyan lo peju pese si TBS lati wo fiimu naa.
A ò lè máa bínú ara wa kí a máa retí ìlọsíwájú ní Nàìjíríà - Ooni Ile Ife
Ọọni parọwa yii lasiko to wa ni igbele ọlọjọ meje to maa n ṣaaju aṣekagba Ọdun Ọlọjọ, ki wọn to gbe ade Are jade lati fi wure fun gbogbo ilu.
'Ẹ má sọ ìrètí nù, díẹ̀ ló kù kí Nàìjíríà dé ibi gíga - Ààrẹ Tinubu
Aarẹ Tinubu sọ pe orilẹede Naijiria ti wa loju ọna ati de ibi giga rẹ, bi ko tilẹ ti I si nibi to yẹ ko wa lọwọlọwọ.
Ìdí tí ẹ kò fi rí mi nínú iṣẹ́ sinimá rèé, ṣùgbọ́n mo ti padà sẹ́nu iṣẹ́ báyìí- Mosun Filani
Ilumọọka oṣere naa sọ pe ''nnkan ti kii jẹ ki ọpọ obinrin to gbe iṣẹ sori gbe ile ọkọ ni pe wọn kii le yẹba pẹlu iṣẹ wọn fun idile.
Wo ọ̀nà márùn-ún tí o lé gbà dènà ibà ọ̀rẹ̀rẹ̀ (Lassa Fever) tó ti ṣekúpa èèyàn 259 báyìí
NCDC ni awọn ipinlẹ ti akọsilẹ sọ pe awọn eeyan ti ṣẹṣẹ lugbadi arun lassa fever ni ipinlẹ Ondo, Edo ati Kogi.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ibo ni ìwádìí dé dúró lórí àgúnmu tó gbẹ̀mí èèyàn 49 l'Ondo?
Akọwe agba ileeṣẹ eto ilera ipinlẹ naa, Ayodele Ojo Adiji, lo fidi iroyin naa mulẹ.
Wo àwọn ilẹ̀ àti dúkìá tí ìjọba àpapọ̀ ṣèkìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ rà ní ìpínlẹ̀ Oyo
Ninu atẹjade kan ti Shuaib Belgore, ẹni to jẹ akọwe agba fun ileeṣẹ to n ri si igbasoke agbegbe ati ibugbe fun ijọba apapọ, iyẹn Federal Ministry of Housing and Urban Development ni wọn ti ṣekilọ naa.
Wo àwọn iṣẹ́ tí ìjọba UK gbé jáde táwọn èèyàn fi lè gba físà wọ orílẹ̀ èdè náà
Gẹgẹ bi Home Office ṣe sọ, ẹni to ba fẹ fi awọn iṣẹ naa wọ UK gbọdọ mọ koodu mẹrin to wa niwaju iṣẹ naa ki wọn to wo o boya wọn le forukọ silẹ fawọn iṣẹ naa.
Èèyàn mẹ́rin wọ gàù fún jíjí ọmọ ọjọ́ mẹ́rin gbé lọ́wọ́ ìyá rẹ̀ tó ní àrùn ọpọlọ
Yatọ si pe wọn ji ọmọ naa ti ko ju ọmọ ọjọ mẹrin gbe bi ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ naa ṣe sọ, wọn tun ta a pẹlu.
INEC fẹ́ẹ́ lo ẹ̀rọ AI fún ìdìbò ọdún 2027, bí yóò ṣe lọ rèé
Chukwuemeka Chukwu, Kọmiṣanna eto idibo nipinlẹ Enugu lo sọ eyi di mimọ lasiko to ṣoju Ọjọgbọn Joash Amupitan, Alaga INEC, nibi eto awọn olootu iroyin to waye l'Enugu lopin ọsẹ.
Ibà Lassa pa èèyan 258 láwọn ìpínlẹ́ kan ní Naijiria, òǹkà ikú lé sí i ní ìdá mẹ́rìnlélógún- NCDC
Alekun ba iye eeyan to ku lọdun yii ju tu asiko yii kan naa ni 2025 lọ bi NCDC ṣe kede. Eeyan 162 ni won lo pa niwoyi ọdun 2025.
Wo àwọn Ààrẹ orílẹ́-èdè mẹ́fà tí wọ́n kò yọjú síbi ìpàdè àjọ àgbáyé UNGA tó n lọ lọ́wọ́ l'Amẹrika
Igba kọkanlelọgọrin ree ti ipade UNGA yoo maa waye, nibi ti awọn olori orilẹede ti maa sọrọ nipa awọn idagbasoke, aiojukọ, ati awọn nnkan miran to kan gbogbo agbaye.
Ilé ẹjọ́ wọ́gilé àṣẹ tí Trump fi de iléeṣẹ́ ìròyìn CNN, MS NOW àti Politico ní White House
Ṣaaju ni Aarẹ Donald Trump ti kọkọ fofin de awọn ileeṣẹ iroyin naa lọjọ Ẹti to kọja lọna ati fi iya jẹ wọn lẹyin to fẹsun kan wọn pe wọn n gbe iroyin ẹlẹjẹ kiri.
Ipa tí ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ mílíọ̀nù lítà bẹntiróòlù tíjọba ní káwọn alágbàtà epo mẹ́fà kó wọlé yóò ní lórí ọmọ Naijiria
Ikede ajọ NMDPRA to n mojuto ẹka epo rọbi ni Naijiria fi han pe orilẹede Naijiria yoo si maa lo epo ti wọn n fọ lorilẹede yii ati nilẹ okeere ti ọdun yii yoo fi pari.
Fídíò, Tírélà ló pa ọkọ mi tó jẹ́ awakọ̀ èrò, ìdá mẹ́ta ẹ̀bùn owó ló kàn mì, ìyá ọkọ mi kò bèèrè àwọn ọmọ di ìsinyìí - Opó, Duration 5,33
BBC News Yorùbá bá opó mẹ́ta sọ̀rọ̀ láti mọ ohun tí wn là kọjá lẹ́yìn tí ọkọ wọn kú, gbogbo wọn sì ló rí ohun wí.












































































