Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published

Ijọba ipinlẹ Oyo ti kọminu lori awọn ọmọ ipinlẹ naa ti wọn ji gbe lasiko ti wọn n rinrinajọ lọ ipinlẹ Imo ati Akwa Ibọm fun ipagọ agunbanirọ

A gbọ pe ọkọ akero meji to ko awọn ọdọ naa lawọn agbebọn ya bo, ti wọn si dari gbogbo wọn sinu igbo

Ileeṣẹ ọlọpaa ni iṣẹ ti bẹrẹ lati doola wọn

Ẹkunrẹrẹ wa ni bbc.com/yoruba

*************************************************************

Oṣere tiata nni, Ijeoma Otabor ti ọpọ mọ si Phyna yoo gba owo to le ni aadọta miliọnu naira ati ọkọ ayọkẹlẹ tuntun

Lẹyin to fẹṣẹ fọ Nkechi Blessing lẹnu ninu ija ẹṣẹ kikan wọn to waye niluu Eko

Ipele kẹrin ni ija naa de ti Nkechi ti ṣubu yakata lẹyin ti Phyna fi ikuku ranṣẹ si

************************************************************

O di gbere, o darinako, o tun doju ala firi

Wọn ti ṣeto isinkun agba oṣere nni, Olu Jacobs

Ọpọ oṣere tiata, araalu ati oloṣelu lo yọju sibi eto isinku naa to waye lagbegbe Lekki

Fun ẹkunrẹrẹ