Ǹjẹ́ ó tọ́ kí òbí máa kàn án ní dandan f'áwọn ọmọ láti tọ́jú wọn lọ́jọ́ ogbó?
Ǹjẹ́ ó tọ́ kí òbí máa kàn án ní dandan f'áwọn ọmọ láti tọ́jú wọn lọ́jọ́ ogbó?
Published
Ọpọ lo maa n gbadura pe ki awọn jẹun ọmọ ṣugbọn ohun to n lọ kiri lode oni ko fi ara jọ pe o n fẹ ri bẹẹ. ohun ti ọpọ awọn ọmọ n sọ ni pe, awọn gan o tii ri ọwọ họ ori tabi jẹun kanu debi pe awọn a maa fi ranṣẹ si obi nibi kan.
awọn to ba BBC News Yoruba sọrọ lori eyi ṣe alaye ọtọọtọ lori rẹ ati iha to kọ si wọn.