BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Ojú ewé to wà yìí,
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ojú ewé to wà yìí,
Fídíò
Fídíò
9:58
Fídíò,
Ẹgbẹ́ wa ló gbé Tani Ọlọhun' ṣùgbọ́n ìjọba ló gbé e wá sí Ilorin, Ẹgbẹ́ tó ń bá Tani Ọlọhun ṣẹjọ́ ní Ilorin ṣàlàyé
, Duration 9,58
23 Ògún 2023
Ọ̀pọ̀ tó ro Super Falcons pin ní ìdíje World Cup tó kọjá la jọ lójú ní Australia – Asisat Oshoala
22 Ògún 2023
7:55
Fídíò,
Mo ṣe amúgbálẹ́gbẹ́ fún Ooni Ile Ife kí n tó di olorì – Olorì Aderonke Ademiluyi Ogunwusi
, Duration 7,55
21 Ògún 2023
1:23
Fídíò,
Ẹ̀ wo ayàwòrán tó kọ́ ilé rẹ̀ bíi ‘’camera’’ tó sì sọ àwọn ọmọ rẹ̀ ní orúkọ àwọn ‘’camera’’
, Duration 1,23
19 Ògún 2023
8:31
Fídíò,
Inú wa kò dùn pé a bí ìbẹrin, ọ̀dá owó ní kò jẹ́ ká ṣẹ́ oyún náà níbẹ̀rẹ̀ - Bàbá Ìbẹrin
, Duration 8,31
10 Ògún 2023
8:50
Fídíò,
"Ọmọ ìyá oníbúrẹ́dì ni mí, ilé pákó la gbé dàgbà kí ń tó di gbajúmọ̀ akọrin"
, Duration 8,50
8 Ògún 2023
BBC tú àṣírí ilé tí wọ́n ti ń fi pàṣán bó ìdí àwọn arúgbó
7 Ògún 2023
7:51
Fídíò,
Ìtàn odò Yemojì rèé, obìnrin arìnrìnàjò tó di odò tó ń ṣe ìwòsàn
, Duration 7,51
7 Ògún 2023
6:29
Fídíò,
Kazeem Dosunmu, Alfa tó fi owó ilé ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ kọ́ afára fún ìlú rẹ̀
, Duration 6,29
1 Ògún 2023
10:27
Fídíò,
Kò sí bí ológun tún ṣe lè rí ìjọba gbà mọ́ lórílẹ̀èdè Nàìjíríà - Ọ̀gágun Adisa Raji, gómìnà ológun nígbàkanrí
, Duration 10,27
31 Agẹmo 2023
2:00
Fídíò,
Ìlù gángan ni a fi ń ṣe iṣẹ́ ìhìnrere àṣà Yoruba f'àwón ọmọde- Adebayo Ayodeji
, Duration 2,00
26 Agẹmo 2023
3:48
Fídíò,
N kò nílò ọtí tàbí sìgá kí n tó wa ọkọ̀ ńlá Tírélà bí àwọn yòókù- Ademola Taiwo
, Duration 3,48
25 Agẹmo 2023
7:30
Fídíò,
Ọ̀pọ̀ ọ̀rẹ́ kọ mi torí mò ń wọ aṣọ ìbílẹ̀, wọ́n ní nǹkan míì wà nídìí rẹ̀ - Bàbá Àṣà
, Duration 7,30
24 Agẹmo 2023
3:39
Fídíò,
Ẹ̀yin tí mo bá ṣẹ̀, ẹ foríjìmì - Agbako sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ ọ̀gọ́rùn-ún ọdún rẹ̀
, Duration 3,39
23 Agẹmo 2023
4:32
Fídíò,
"Ìjọba yìí kàn ń fara ni wá ni, mo sì ṣe wàhálà lórí rẹ̀, ìnira yìí pọ̀ jù"
, Duration 4,32
20 Agẹmo 2023
2:09
Fídíò,
Ayé ń yí! Wo ìdí tí ọ̀pọ̀ ọkùnrin ṣe ń lọ kọ́ bí a ti ń ṣiṣẹ́ ilé
, Duration 2,09
19 Agẹmo 2023
5:23
Fídíò,
"Àlàyé rèé lórí bí wọ́n ṣe jí Alága APC l‘Ekiti gbé àti bó ṣe gba ìdáǹdè"
, Duration 5,23
18 Agẹmo 2023
9:19
Fídíò,
"Awọn ọmọ tó ń ta ilẹ̀ Ibadan láìtọ́ rugi oyin bí ọba ṣe wà ní ìjọba ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan"
, Duration 9,19
17 Agẹmo 2023
1:53
Fídíò,
Àṣà ìdárayá kan réè tàwọn olùdíje ti ń jẹ́ ìgbájú olóyì ní pápá ìṣiré
, Duration 1,53
15 Agẹmo 2023
1:54
Fídíò,
'Ọyàn àwọn míràn tóbi ṣùgbọ́n kò wúwo bíi tèmi yìí'
, Duration 1,54
12 Agẹmo 2023
3:49
Fídíò,
'Epo ni Mummy ní kí n wá gba, àfi tó da omi gbígbóná lé mi lára pé mò ń fẹ́ ọkọ òun'
, Duration 3,49
11 Agẹmo 2023
5:55
Fídíò,
'Ọkọ mi gé lọ́wọ́, èmi ìyàwó gé lẹ́sẹ̀, ohun táa máa ń sọ fáwọn tó fẹ́ mọ bí eré ìfẹ́ wa ṣe bẹ̀rẹ̀ nìyí'
, Duration 5,55
10 Agẹmo 2023
9:16
Fídíò,
Ọjọ́ tó bà mí nínú jẹ́ jùlọ nilé ayé ni ... - Agbako Charles Olumo
, Duration 9,16
10 Agẹmo 2023
2:42
Fídíò,
Mo lè sọ arúgbó dí ọmọge nígbàkúgbà - Hakeem Effect
, Duration 2,42
9 Agẹmo 2023
Ìṣájú
Page
32
nínú
40
1
29
30
31
32
33
34
35
40
Tókàn