BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Ojú ewé to wà yìí,
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ojú ewé to wà yìí,
Fídíò
Fídíò
Olanrewaju Adepoju fi ewì jà fẹ́tọ̀ọ́ aráàlú, ó tún gbé àṣà Yorùbá lárugẹ - àkọ́bí olóògbé
12 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
1:53
Fídíò,
Omar ọmọ ọdún mẹ́tàlá láti Gaza pàdánù òbí rẹ̀ méjèèjì nínú ìkọlù Israel
, Duration 1,53
10 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
6:38
Fídíò,
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtẹ̀mọ́lẹ̀ ni ojú mi rí gẹ́gẹ́bí àkàndá lẹ́nu iṣẹ́ kí n tó di ‘Perm Sec’ – Ayanwale Kayode, akọ̀wé àgbà nípínlẹ̀ Kwara
, Duration 6,38
9 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
5:54
Fídíò,
Àwọn aṣòfin kò jẹ̀bi pẹ̀lú ọkọ̀ olówógọbọi tí wọ́n fẹ́ rà, owó Naira to yọ̀lẹ ni ká dá lẹ́bi -Mínísítà tẹ́lẹ̀
, Duration 5,54
8 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
4:50
Fídíò,
Mo kọ́ bí igi ṣe ń sọ̀rọ̀ -Arole, agbẹ́gilére
, Duration 4,50
5 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
4:44
Fídíò,
Kàyééfì! ‘Kọ̀rọ̀ Afọ́jú’ ìletò àwọn afọ́jú níbi tí ọmọ afọ́jú kò ti lè jogún òbí rẹ̀
, Duration 4,44
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
3:05
Fídíò,
Wo ìdí tí wọ́n fi ń pe arábìnrin yìí ní Helen Paul Kòlénìyàn
, Duration 3,05
3 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
6:14
Fídíò,
Ọ̀pọ̀ àwọn tó wá ń ṣe àyẹ̀wò DNA ni ilé wọn máa ń dàrú – Onímọ̀ nípa àyẹ̀wò DNA
, Duration 6,14
2 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
'Àwa ò ní gbà o, àyàfi tí ẹ bá fún wa láǹfàní àti máa ṣẹ́yún'
29 Bélú 2023
5:20
Fídíò,
Toyinbo rèé, ọlọ́kadà tó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè pẹ̀lú ‘First Class’ ní fásitì FUNAAB
, Duration 5,20
29 Bélú 2023
5:18
Fídíò,
Mama Kuto rèé, ìyá àgbà awakọ̀èrò tí àìsàn ìyá rẹ̀ sọ̀ di ọmọ gáréèjì
, Duration 5,18
28 Bélú 2023
‘Àwọn ọlọ́pàá pa irọ́ ìdigunjalè mọ́ mi, gbé àwòrán mi sórí ayélujára láì ṣe ìwádìí, mo wá di ẹni tí ẹbí ọ̀rẹ́ ń sá fún’
27 Bélú 2023
6:13
Fídíò,
'Láti ìgbà tí ọkọ mi ti nàmí fún ìgbà àkọ́kọ́ ni kò ti dáwọ́ dúró'
, Duration 6,13
25 Bélú 2023
1:51
Fídíò,
Wo ọkọ̀ Volvo tí Funmilayo Ransome-Kuti lò gbẹ̀yìn, kó tó jáde láyé
, Duration 1,51
23 Bélú 2023
7:32
Fídíò,
Yèyé Osun méjì tó rí àtákò ẹ̀sìn n‘Ilorin sọ ìrírí wọn àti bí ọ̀kan ṣe di Mùsùlùmí padà
, Duration 7,32
22 Bélú 2023
7:14
Fídíò,
"Mo kọ́ iṣẹ́ Mẹ́kálíkìì ọ̀kadà lẹ́yìn ìwé mẹ́fà àmọ́ mo kẹ́kọ̀ọ́ gboyè dìgírì méjì fúnra mì i"
, Duration 7,14
21 Bélú 2023
5:12
Fídíò,
Bàtà mi ẹsẹ̀ kan làwọn ìkà lò láti mú kí ẹsẹ̀ mi méjèèjì rọ - Grace Garuba
, Duration 5,12
20 Bélú 2023
1:44
Fídíò,
Kàyééfì! Wo bi Israel ṣe ń lo ẹyẹ ìdì láti wá òkú àwọn tó bá ìkọlù Hamas lọ
, Duration 1,44
18 Bélú 2023
4:09
Fídíò,
Wo arábìnrin tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ mọ́ín-mọ́ín pẹ̀lú N500, ti ó sì rán ọmọ ní fásítì, ra ọkọ̀, kọ́’lé níbẹ̀ lónìí
, Duration 4,09
16 Bélú 2023
2:11
Fídíò,
Wo ilé ìgbọ̀nsẹ̀ tí kò lo omi rárá, ike àti gíláàsì tí wọn kò lò mọ́ ni wọ́n fi ṣe é
, Duration 2,11
15 Bélú 2023
Abẹ́rẹ́ mẹ́rin sí mẹ́jọ ni mo máa ń gbà lójúmọ́ torí àrùn ìtọ̀ ṣúgà - Adewumi
14 Bélú 2023
Ǹjẹ́ ó ṣe kókó pé kí èèyàn ta ilé rẹ̀ lọ òkè òkun? Adekola Adesina sọ ìrírí rẹ̀
12 Bélú 2023
3:38
Fídíò,
Àwọn ọ̀nà láti fi dá ìròyìn òfégè mọ̀ lásìkò ìbò 2023
, Duration 3,38
10 Bélú 2023
4:08
Fídíò,
Àwọn nǹkan tí o gbọ́dọ̀ mọ̀ kí o tó lọ sí ibùdó ìdìbò nìyí
, Duration 4,08
10 Bélú 2023
Ìṣájú
Page
29
nínú
40
1
26
27
28
29
30
31
32
40
Tókàn