You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Èyí ni àkójopọ̀ èsì ìdìbò gómìnà láti ìpínlẹ̀ Osun
Bi idibo si ipo gomina nipinlẹ Osun ṣe waye lọjọ Abamẹta, ọjọ kẹẹẹdogun oṣu Kẹjọ ọdun 2026 yii ni ajọ eleto Idibo ilẹ wa, INEC, ṣe ti n ko esi ibo naa jọ.
Bẹẹ naa si ni BBC News Yoruba to ti gunlẹ sipinlẹ Osun ṣaaju ọjọ idibo n mu gbogbo ẹ wa bo ṣe n lọ.
Eyi ni awọn esi idibo naa bi wọn ṣe n jade lati ijọba ibilẹ kọọkan l'Osun.
Lati maa mọ bi esi idibo naa ṣe n lọ si, maa ba wa lọ lori ikanni ati oju opo yii.
Ni bakanaa, ti o ba ṣe n tẹ ori atẹ esi ìbo to wa ni isalẹ patapata, ni abajade esi ibo fun ẹgbẹ oṣelu kọọkan, pẹlu ijọba ibilẹ ti wọn ti bori, yoo maa han si ọ.
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ilesha East LGA
Accord 12280
ADC 504
APC 16208
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ifedayo LGA
Accord 7427
ADC 115
APC 6836
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ilesha West LGA
Accord 16196
ADC 673
APC 12756
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ife North LGA
Accord 13879
ADC 333
APC 9613
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ede South LGA
Accord 26188
ADC 390
APC 6219
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Boluwaduro
Accord 7118
APC. 7050
ADC 179
Ajọ INEC ti fẹ bẹrẹ kika esi idibo
Gbogbo eto ti to ni Osogbo nibi ti ajọ INEC tí fẹ bẹrẹ si ni maa ka esi idibo ipinlẹ Osun tó waye loni.