Queen Elizabeth II burial: Àwòrán bí ìsìnkú Ọbabìnrin Elizabeth ṣe lọ nìyíí

Ọba Charles III, Ọmọbabinrin Anne, ỌmọbakunrinAndrew ati Ọmọbakunrin Edward
Published

Awọn alejọ lati orilẹede aka aimoye lo pejọ pọ si ibi isinku Ọbabinrin Elizabeth II ni Ọjọ Kọkandinlogun, Oṣu Kẹsan, ọdun 2022.

Awọn ara ile ọba to fi mọ Ọba Charles lo n rin pẹlu ibanujẹ nitori iku iya rẹ.

Ọmọbakunrin William
Ọmọbakunrin Harry
Catherine Middleton
Ayaba Camilla
Meghan, Duchess of Sussex arrive for di State Funeral of Queen Elizabeth II at Westminster Abbey on September 19, 2022 in London, England
Àkọlé àwòrán, Meghande si ibi isinku Ọbabinrin Elizabeth II
Sarah, Duchess ti York,Ọmọbabinrin Beatrice ati Edoardo Mapelli Mozzi ni Ọjọ isinku ni Westminster Abbey.
Àkọlé àwòrán, Sarah, Duchess ti York,Ọmọbabinrin Beatrice ati Edoardo Mapelli Mozzi ni Ọjọ isinku ni Westminster Abbey.

Ọmọbabinrin Charlotte ati Ọmọbakunrin George darapọ mọ mọlẹbi wọn lati ṣe ayẹyẹ ikẹyin fun iya-baba- baba wọn.

Ọmọbakunrin Wales, William, iyawo rẹ, Catherine,awọn ọmọ wọn George ati Charlotte
Catherine, Charlotte ati George
Ọmọbabinrin Charlotte
Ayaba Camilla, Catherine,, George n tẹsiwaju lọ si ibi isinku

Ọba Charles ati awọnb mọlẹbi ọba kọkọ wa ọkọ lọ si Westminster Hall ki wọn to to tẹle oku Ọbabinrin Elizabeth naa lọ si abbey.

Ayaba Camilla, Catherine,, George n tẹsiwaju lọ si ibi isinku
Posi Ọbabinrin Elizabrth wa lori apele saaju isin isinku
Àkọlé àwòrán, Posi Ọbabinrin Elizabrth wa lori apele saaju isin isinku
Ọba Charles III,Ọmọbakunriin Andrew ati Ọmọbabinrin Anne ni Westminster Abbey
Idile ọba darapọ mọ ila lati ṣayẹyẹ ikẹyin fun Ọbabinrin Elizabeth
Àkọlé àwòrán, Idile ọba darapọ mọ ila lati ṣayẹyẹ ikẹyin fun Ọbabinrin Elizabeth
Ọba Charles bẹri fu n Ọbabinrin Elizabeth
Àkọlé àwòrán, Ọba Charles bẹri fu n Ọbabinrin Elizabeth

Awọn alejo to le ni ẹgbẹrun meji 2,000 ni wọn parapọ si Westminster Abbey fun eto isinku naa.

Awọn ikọ ologun Ọbabinrin Elizabeth
Awọn pasitọ n duro de posi Ọbabinrin Elizabeth.
Ọba Charles III, ayaba , Vice Admiral Sir Tim Laurence,Duke York, Earl Wessex, Countess ti Wessex, Duke ti Sussex, Duchess ti Sussex, Beatrice, Edoardo Mapelli Mozzi ati Lady Louise Windsor ati James, Viscount Severn, Samuel Chatto, Arthur Chatto, Lady Sarah Chatto, Daniel Chatto ati Duchess ti Gloucester niwaju oku Ọbabinrin Elizabeth.

Aarẹ Ilẹ Faranse, Emmanuel Macron, Aarẹ Ilẹ Amerika,Joe Biden ati Olotu Ijọba Canada, Justin Trudeau wa lara awọn adari orilẹede to wa nibẹ.

Brigitte Macron ati Emmanuel Macron ni Westminster Abbey
Aarẹ Ilẹ Amẹrika, Joe Biden ati iyawo rẹ nibi isinku ni London
Olootu Ijọba ilẹ Canadan pẹlu iyawo rẹ, Justin Trudeau ati Sophie Gregoire Trudeau ni ibi isinku naa
Àkọlé àwòrán, Olootu Ijọba ilẹ Canadan pẹlu iyawo rẹ, Justin Trudeau ati Sophie Gregoire Trudeau ni ibi isinku naa

Olotu ilẹ Gẹẹsi, Liz Truss ati awọn olootun ijọba miran wa nibẹ

Olootu Ijọba Ilẹ Gẹẹsi, Liz Truss ati Hugh O'Leary n lọ si ibi isinku naa.
Àkọlé àwòrán, Olootu Ijọba Ilẹ Gẹẹsi, Liz Truss ati Hugh O'Leary n lọ si ibi isinku naa.
Awọn Olootu Ilẹ Gẹẹsi tẹlẹri joko papọ nibi eto isinku naa.

Lady Pamela Hicks to ṣiṣẹ gẹgẹ bi alabojuto Ọbabinrin Elizabeth II, wa lara awọn alejo ni Westminster.

Lady Pamela Hicks

Gbogbo aworan lo gba ontẹ.