Ṣé ìwọ láyà ti o mọ òwe Yorùbá dáadáa?

awọn obinrin
Àkọlé àwòrán, Aṣa Yoruba dùn pupọ
Published

Eyi ni akojọpọ diẹ lara awọn òwe ti BBC Yorùbá ti lò sẹyin.

Tẹ ibi yii ki o dahun bi o ṣe yẹ.

  • Ààbò ọ̀rọ̀ làá sọ f'ọ́mọlúàbí tó bá dé núẹ̀ á di odidi
  • Bíná bá kú á fi eérú b'ojú
  • Àì tètè m'ólè olè ń m'olóko
  • Alágẹmọ ti bímo rẹ̀ ná àìmọ̀ọ́jó kù sí ọwọẹ̀
  • B'ígbín bá fà ìkarahun a tẹ̀le
  • Ẹni a sùn tì là ń jarunpá lù
  • B'ọ́mọ́dé bá kọ iyán alé àgbà a f'ìtàn balẹ̀
Àkọlé fídíò, Oduduwa Alphabet: òmìnira èdè ti dé fún Port Novo báyìí