Olúwa ló darí Ooni sí mi, ìdí iṣẹ́ ìráńṣẹ́ ni wọ́n ti pàdé mi - Naomi Ogunwusi

Àkọlé fídíò, Olúwa ló darí Ooni sí mi, ìdí iṣẹ́ ìráńṣẹ́ ni wọ́n ti pàdé mi - Naomi Ogunwusi
Olúwa ló darí Ooni sí mi, ìdí iṣẹ́ ìráńṣẹ́ ni wọ́n ti pàdé mi - Naomi Ogunwusi
Published

Oríṣiríṣi àhesọ̀ ọ̀rọ̀ ló ti ń wáyé lórí bí Ooni Adeyeye Ogunwusi àti olorì rẹ̀ nígbà kan, Naomi Silekunola ṣe pàdé.

Olorì Naomi sọ pé Oluwa ló darí Ooni sí òun, ìdí iṣẹ́ ìránṣẹ́ sì ni wọ́n ti pàdé.

Ó sọ èyí lórí àkànṣe ètò BBC Yoruba, Bó ṣe ń lọ.