BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Iwa-ipa
Gómìnà Ìjọba Ogun ní kí ọba tó dá olóyé dọ̀bálẹ̀ níta gbangba lọ rọ́ọ́kún nílé, ọlọ́pàá fọ̀rọ̀ wá Kábíyèsí lẹ́nu wò
4 Èrèlè 2025
Ọba alayé tí àwọn jàǹdùkú lù l'Osun, bó ṣe jẹ́ gan-an rèé
7 Sẹ́rẹ́ 2025
Ọwọ́ Ọlọ́pàá tẹ afurasí 19 to lọ́wọ́ sí rògbòdìyàn tó wáyé nílùú Owo
7 Sẹ́rẹ́ 2025
Awakọ̀ wa ọkọ̀ wọ inú ọjà ọdún Kérésìmesì, èèyàn 200 farapa
22 Ọ̀pẹ̀̀ 2024
Ọkùnrin tó dáná sun ara rẹ̀ àti ìyàwó l'Ondo jáde láyé, ìyàwó dèrò ilé ìwòsàn
15 Ọ̀pẹ̀̀ 2024
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn ọmọlẹ́yìn ààrẹ tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ dìbò yàn ní Ghana tó ń dá rògbòdìyàn sílẹ̀
11 Ọ̀pẹ̀̀ 2024
Ohun tí a mọ̀ nípa ìkọlù àwọn agbésùnmọ̀mí tó gbẹ̀mí èèyàn 32 l’étíkun kan ní Somalia
3 Ògún 2024
Wo bí o ṣe lè dáàbò bo ara rẹ lásìkò ìwọ́de tó ń bọ̀ kí o má baà fara káásá
30 Agẹmo 2024
Èèyàn mẹ́wàá ló ti kú níbi ìkọlù ọlọ́pàá àtàwọn ọ̀dọ́ ‘Gen Z’ tó ń ṣèwọ́de
25 Òkùdu 2024
'Ojoojúmọ́ ni wọ́n ń ja àwọn èèyàn lólè tàbí pa wọn, mò ń gbàdúrà lọ́sàn-án àti lóru fún ààbò'
14 Èbibi 2024
Ìjọba Nàíjíríà sọ̀rọ̀ lórí ikú Daniel Anjọrin ọmọ ọdún mẹ́rìnlá tí wọ́n gún pa ní London
4 Èbibi 2024
Kí ló fa aáwọ̀ tó jẹ́ káwọn afurasí jàndùkú dáná sun ọjà Ile-Epo l'Eko?
3 Èbibi 2024
Rògbòdìyàn bẹ́ sílẹ̀ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ẹlẹ́wọ̀n fẹṣẹ̀ fẹ
5 Ẹrẹ̀nà 2024
Ọmọọba ti ṣáájú lérí láti pa Adeoriokin tipẹ́ - Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Adeoriokin
31 Sẹ́rẹ́ 2024
Àlùbamí ni ọkọ mi tẹ́lẹ̀ máa ń lù mí tí Man United bá ti fìdírẹmi - Ìlúmọ̀ọ́ká òṣèbínrìnrin
30 Sẹ́rẹ́ 2024
Ọlọ́pàá mú ajìjàgbara Yorùbá Nation l’Eko lẹ́yìn ọdún kan tí wọ́n ti ń wá a
26 Sẹ́rẹ́ 2024
Kí ló wà nínú lẹ́tà tí àwọn ẹgbẹ́ òkùnk̀un tún kọ sí Ákárìgbò Rẹ́mọ?
25 Sẹ́rẹ́ 2024
Wọ́n gé orí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin ọmọ Kenya, ọlọ́pàá mú afurasí ọmọ Nàìjíríà méjì
23 Sẹ́rẹ́ 2024
Àwọn ọmọ ẹgbẹ̀ òkùnkùn kọ lẹ́tà sáwọn ọba ní ìpìnlẹ́ Ogun
14 Sẹ́rẹ́ 2024
Àwọn ọmọẹ̀yìn àwọn olóṣèlú alátakò ń kojú àwọn ọlọ́pàá lẹ́yìn ìbò ààrẹ lórílẹ̀èdè DRC
28 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Àjọ̀dùn Kérésì di ìbánújẹ́ ní Plateau, àwọn agbébọn tún ṣekúpa èèyàn 115
26 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Obìnrin tó da omi gbígbóná lé ọkọ rẹ̀ lórí ẹ̀sùn pé ó ń yàn àlè yóò ṣe kérésì ní àtìmọ́lé
25 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Èèmọ̀ wọ̀'lú: Ọmọ ọdún mẹ́tàlélógún pa bàbá rẹ̀ tó jẹ́ Olóyè ìlú ní Kwara, ó kun ún wẹ́lẹ wẹ̀lẹ bíi adíyẹ Kérésì
22 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Àwọn agbébọn jí Baálẹ̀ àtàwọn mẹ́tàlélógún míràn gbé ní Taraba
20 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Ìṣájú
Page
4
nínú
6
1
2
3
4
5
6
Tókàn