BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Kwara
Àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara da ṣẹ́ sílẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì oníkìlọ̀ ọlọ́jọ́ méjì.
19 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Ó gbẹnután! Alfa Musa pokùnso ní Ilorin, Ó ní Ọlọ́run kò gbọ́ àdúrà òun
9 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
6:38
Fídíò,
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtẹ̀mọ́lẹ̀ ni ojú mi rí gẹ́gẹ́bí àkàndá lẹ́nu iṣẹ́ kí n tó di ‘Perm Sec’ – Ayanwale Kayode, akọ̀wé àgbà nípínlẹ̀ Kwara
, Duration 6,38
9 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
5:54
Fídíò,
Àwọn aṣòfin kò jẹ̀bi pẹ̀lú ọkọ̀ olówógọbọi tí wọ́n fẹ́ rà, owó Naira to yọ̀lẹ ni ká dá lẹ́bi -Mínísítà tẹ́lẹ̀
, Duration 5,54
8 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Owó ìsákọ́lẹ̀ fa làásìgbò láàrín àwọn Hausa nílùú Babanla ní Kwara
6 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
4:44
Fídíò,
Kàyééfì! ‘Kọ̀rọ̀ Afọ́jú’ ìletò àwọn afọ́jú níbi tí ọmọ afọ́jú kò ti lè jogún òbí rẹ̀
, Duration 4,44
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Seriki Fulani, èèyàn méjì míì tó jẹ̀bi ẹ̀sùn ìjínígbé gba ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n gbéré
1 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Ẹ̀ẹmàrún ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni mo ti pààrà ilé ẹjọ́ látìgbà tí mo ti gbégbá ìbò àmọ́... - Rukayat Shittu
29 Bélú 2023
Ó ṣe! Baálé ilé kó sódò n'Ilorin, pàdánù ẹ̀mí rẹ̀
28 Bélú 2023
Wọ́n gbé àwọn ìlànà tuntun kalẹ̀ fún Tani Olohun láti bọ́ nínú ẹ̀sùn ìbánilórúkọjẹ́
27 Bélú 2023
ìjàńbá iná ṣẹlẹ̀ n'Ilorin, ọjà ọdún àìmọye Naira jóná ráúráú
24 Bélú 2023
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí kan lórí ikú akẹ́kọ̀ọ́ Offa poly
20 Bélú 2023
Wo ìdí tó ṣe pọn dandan fún obìnrin láti ṣègbéyàwó ọlọ́pọ̀ èrò ní ìlú Shao
19 Bélú 2023
4:09
Fídíò,
Wo arábìnrin tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ mọ́ín-mọ́ín pẹ̀lú N500, ti ó sì rán ọmọ ní fásítì, ra ọkọ̀, kọ́’lé níbẹ̀ lónìí
, Duration 4,09
16 Bélú 2023
Ìyanṣẹ́lódì ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ní Nàìjíríà mú ìfàsẹ́yìn bá ìgbẹ́jọ́ Tani Olohun
14 Bélú 2023
Ẹgbẹ́ Mọdirasatu Mohammed Ilọrin tún pe Tani-Ọlọhun lẹ́jọ́ fún dídáná sun Kurani nígbá kan
8 Bélú 2023
Ilé ẹjọ́ gíga pa ẹjọ́ tí Tani-Olohun pé láti ṣàgbéyẹ̀wò ọ̀rọ̀ béèlì rẹ́
2 Bélú 2023
Barber wọ gàù lẹ́yìn tí ọ̀rẹ́bìnrin kú lásìkò ìbálòpọ̀ gbọ́ọ̀rọ̀
1 Bélú 2023
Àwọn Jàǹdùkú yabo Radio Nàìjíríà, jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan gbé lọ, lù ẹsọ alabo.
1 Bélú 2023
Wo bí obìnrin tó di odò ṣe gbé ọdún Awonga kalẹ̀ sí ìlú Shao níbi tí wọ́n ti ń fi ọ̀pọ̀ omidan f'ọ́kọ
30 Ọ̀wàrà 2023
Igi Àràbà ya lulẹ̀ n'Ilorin, èèyàn méjì kú lójú ẹsẹ̀, márùn-ún farapa yána-yàna
24 Ọ̀wàrà 2023
Tani-Olorun wọ wàhálà tuntun n‘Ilorin, Alfa míì pè é lẹ́jọ́ síléẹjọ́ kẹta
23 Ọ̀wàrà 2023
Adájọ́ bínú dìde kúrò níbi ìgbẹ́jọ́ ‘Tani Olohun’, àlàyé rèé
20 Ọ̀wàrà 2023
Àwọn èèyàn jáde lónìí fún ayẹyẹ ọdún Ifa nílùú Shao
20 Ọ̀wàrà 2023
Ìṣájú
Page
12
nínú
21
1
9
10
11
12
13
14
15
21
Tókàn