BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ere ori Itage
3:23
Fídíò,
Wo bí wọn ṣe ya sinimá ‘Owó orí ẹlẹ́wọ̀n’, tó kọ́ wa láti máṣe gbé ara lé ọ̀rẹ́
, Duration 3,23
3 Ọ̀wàrà 2020
Kí ló ń fa wàhálà láàrín Kunle Afolayan àti Mike Ezuruonye lórí ayélujára?
28 Owewe 2020
Ẹ gbà mí, Nàíjíríà gbá mi lórí àyẹ̀wò Covid-19 - Iyabo Ojo figbe ta
28 Owewe 2020
Ìkébé mi tóbí ju ohun tí mo lè dọwọ́ bò lọ, n kìí fí ṣakọ- Nkechi Blessing
26 Owewe 2020
Yatọ̀ sí pé ó ṣe sọ́jà, tó tún jẹ́ ọkọ Oriṣabunmi, wo àwọn nkan tí o kò mọ̀ nípa Jimoh Aliu
18 Owewe 2020
Ọdún mọ́kànlá rèé témi àti ọkọ mi bẹ̀rẹ̀ ìfẹ́ láti ilé ẹ̀kọ́ girama - Bukunmi Oluwasina
17 Owewe 2020
Òṣèré méjì yìí ń fi ẹ̀wọ̀n runmú tóríi fíìmù "Ife" táwọn obìnrin ń bá ara wọn lòpọ̀
16 Owewe 2020
Àgbàọ̀jẹ̀ òṣèré Shan George ṣetán láti ṣègbéyàwó pẹ̀lú ọkọ kẹẹ̀rin lẹ́ni ọdún 50
15 Owewe 2020
Iṣẹ́ wo ni Ayo Akinwale ṣe sílẹ̀ kó tó rọ̀run àrèmabọ̀ lẹ́ni ọdun 69?
14 Owewe 2020
Mercy Aigbe ṣá ọmọ rẹ̀ sínúu fíìmù tuntun, wo itú tí ọmọ ọdún mẹ́wàá náà pa
13 Owewe 2020
Ọkọ mi kò fẹ́ràn oúnjẹ òyìnbó àfi ti ìbílẹ̀ - Lizzy Anjorin
13 Owewe 2020
Wo fọ́tò àrà MC Oluomo, Pasuma àtàwọn òṣèré tíátà míì níbi ìṣílé Iyabo Ojo
11 Owewe 2020
Ìjà ẹgbẹ́ òṣèré TAMPAN àti ANTP ni kò jẹ́ kí wọ́n pe Baba Legba sínú eré mọ́, kó tó kú - Owolabi Ajasa
8 Owewe 2020
Tí òṣèré tíátà yóò fi kú, eré ni wọn yóò ló ń ṣe - Ibrahim Chatta
8 Owewe 2020
Gbajúgbajà òṣèré “Blue film'' wọ gàù ẹ̀sùn fífipá bá obìrin 13 lòpọ̀
2 Owewe 2020
Ìwọ tó ń ṣí ara sílẹ̀ lọ ṣọ́ọ̀ṣì, ṣé apàyàn kọ́ ni ẹ́ báyìí?- Mike Bamiloye
1 Owewe 2020
Ta ni ìyàwó Chadwick Boseman, tó jẹ́ àwòkọ́ṣe rere f'áwọn ọ̀dọ́ Adúláwọ̀?
31 Ògún 2020
3:44
Fídíò,
'Mí ò lérò pé àwọ́n ọmọ mi lè dé ibi kankan látara eré Tíátà ṣùgbọ́n wọ́n ti de orílẹ̀èdè 27 lágbàáyé'
, Duration 3,44
29 Ògún 2020
Aráyé ẹ gbà mí, nǹkan ń ṣe mí, èyí tó ju àìsàn lọ - Kanran
26 Ògún 2020
Ọkọ Funke Akindele kó eléré àti òṣìṣẹ́ jọ fi ṣe "Surprise Pato" fún un lọ́jọ́ ìbí rẹ̀
25 Ògún 2020
Ariwo ló ń mú owó wọlé fún mi, kò wù mí láti gbé ayé tó dákẹ́ rọ́rọ́ - Lizzy Anjorin
22 Ògún 2020
4:42
Fídíò,
Ó ṣe mí ní àánú fún ọmọ Yorùbá tí kò le sọ èdè abínibí rẹ́ - Ọmọ Igbo Chukwuka
, Duration 4,42
22 Ògún 2020
Ikú Williams Aanuoluwa lágbo òṣèré hú ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ síta
19 Ògún 2020
Olólùfẹ́ mi ṣèèsì fi ọkọ́ gbá mi sí gọ́tà, mo rò pé ọlọ́jọ́ dé ni - Iya Osogbo
19 Ògún 2020
Ìṣájú
Page
26
nínú
32
1
23
24
25
26
27
28
29
32
Tókàn