BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
iwa ọdaran lori itakun agbaye
Ènìyàn mẹ́rin kú lásìkò tí wọ́n ń lé olè tó ja àwọn oní PoS lólè n'Ibadan
28 Ẹrẹ̀nà 2022
Tọkọtaya kó sí gbaga ọlọ́pàá f'ẹ́sùn jíjí ọmọ ọjọ́ mẹ́fà gbé
26 Ẹrẹ̀nà 2022
Olùdásílẹ̀ ìjọ tí ọlọ́pàá FBI ti ń wá fọ́jọ́ pípẹ̀, kó sí gbaga EFCC lórí ẹ̀sùn wáyá-wayà
18 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ gbà mi o, àwọn oníjìbìtì ayélujára ti ń bèèrè ìrànwọ́ lórúkọ́ mi - Kemi Afolabi lọgun
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí adigunjalè márùn ùn níbi tí wọn ti ń jalè ní Ogere
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Malami pahùndà lórí ọ̀rọ̀ Kyari, ó ní kò jẹbi ẹ̀sùn kíkówó pamọ́
13 Ẹrẹ̀nà 2022
Wọ́n ti gbé dẹ́rẹ́bà ọ̀kọ̀ BRT tí Bamise wọ̀ lọ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n Kirikiri
11 Ẹrẹ̀nà 2022
Sé Nàìjíríà le fi Abba Kyari ráńṣẹ́ sí Amẹ́ríkà pẹ̀lú bó ṣe ń kojú ìgbẹ́jọ́ àjọ NDLEA? – Àlàyé rèé
4 Ẹrẹ̀nà 2022
Kíni ó wà nínú lẹ́tà tí ọkùnrin tí wọ́n bá òkú rẹ̀ pẹ̀lú obìnrin kan nínú mọ́tò kọ sí aya rẹ̀?
3 Ẹrẹ̀nà 2022
Ewé sunko fàwọn oníjìbìtì ayélujára mẹ́ta, wò dúkìá tí wọ́n jọwọ fún ìjọba
2 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ̀bẹ̀ béèlì Abba Kyari kò ba mọ́, yóò lo ọjọ́ mẹ́rìnlá si ní àhámọ́ NDLEA - Iléẹjọ́
28 Èrèlè 2022
Ilé ẹjọ́ ju Evans ajínigbé sẹ́wọ̀n gbére
25 Èrèlè 2022
12:14
Fídíò,
Àwọn ti a jọ ń 'robb' lo pa Ìyá mi sínú ẹ̀jẹ̀ ní 'Mission House'- Alufaa Oluwasegunfunmi
, Duration 12,14
17 Èrèlè 2022
Wo ohun méjé tó yẹ kí o mọ̀ nípa Abba Kyari, ọ̀gá ọlọ́pàá tí wọ́n fẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn kàn
15 Èrèlè 2022
Àwọn ẹbí Rahmon Adedoyin àti Timothy Adegoke ju òkò ọ̀rọ̀ lu ara wọn nílé ẹjọ́
5 Èrèlè 2022
Wo ìdí tí ilé ẹjọ́ ilẹ̀ America fi sún ọjọ́ ìdájọ́ Hushpuppi síwájú
4 Èrèlè 2022
Ọ̀gá ọlọ́pàá tó ń wo ìhòhò obìnrin dèrò ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́ta
21 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọkùnrin kan ná N20m tó ṣèèsi wọ inú àkáùǹtì rẹ̀, ó forí kó ẹjọ́
20 Sẹ́rẹ́ 2022
Ilé ẹjọ́ gbà béèlì ìgba mílíọ̀nù Naira(N200m) lórí ẹsùn tí EFCC fi kàn Mompha
18 Sẹ́rẹ́ 2022
Wo bí afurasí ọmọ Nàìjíríà ṣe lu ìlú kan ní Canada ní jìbìtì $500,000
14 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọkùnrin tó gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú ìya rẹ̀ láti fi àbúrò rẹ̀ ṣẹ́ṣó kó sí gbaga Ọlọ́pàá
14 Sẹ́rẹ́ 2022
Baba fẹ́ ta ọmọ rẹ̀ fi ra alùpùpù, ọwọ́ bá tẹ̀ ẹ́ ní Liberia
9 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọmọkùnrin tó fẹ́ kọ́ṣẹ́ Yahoo wá sọ́dọ̀ wa lẹyìn tó mu Colorado tán ló bá kú- Afurasí ọmọ Yahoo
2 Sẹ́rẹ́ 2022
Èmi àti ọmọ ẹgbẹ́ akọrin wa jọ yó ìfẹ́ ara wa ni - Pásítọ̀ ní òun kò jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábáni lòpọ̀
16 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ìṣájú
Page
6
nínú
12
1
2
3
4
5
6
7
8
9
12
Tókàn