BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Aworan Fiimu
Ẹ wo ẹni tó ń jẹ́ Suwebatu nínú ẹbí Baba Suwe àti ohun tó sọ nípa olóògbé
25 Bélú 2021
Bàbá mi máa ń sunkún torí bí kò ṣe le padà ṣeré tíátà mọ́ - Ọmọ Baba Suwe
24 Bélú 2021
Awuyewuye súyọ lórí fídíò òkú Baba Suwe tó lu ayelujára pa
23 Bélú 2021
Àìsàn ‘Dementia’ ló ń bá ọkọ́ mi Olu Jacobs fínra láti ọdún díẹ̀ - Joke Silva
21 Bélú 2021
Lẹ́yìn Titi Masha, Kwam 1 gbé ìyàwó tuntun, Emmanuella Ropo l'Abeokuta, bó ṣe lọ rèé
19 Bélú 2021
Kwam 1 dá àwọn tó ń wọ́ ọ tuurutu nílẹ̀ pé ó jẹ́ gbèsè dollar iṣẹ́ orin kan l'Amẹ́rika
12 Bélú 2021
Wo ohun tí ọkọ àti ìyàwó, Lateef Adedimeji àti Bimpe fi síta fúnra wọn to fihàn pé ọjọ́ ti súnmọ́
9 Bélú 2021
6:47
Fídíò,
Ṣe ọmọ táa bí "fine" ni ìyàwó mi ń bèrè, mo tún ń pa á lẹ́rìín kó má mọ̀ pé ọmọ ti kú - Woli Agba Ayo Ajewole
, Duration 6,47
9 Bélú 2021
Ṣé lóòtọ́ ni Lateef Adedimeji àti Bimpe Oyebade fẹ́ ṣègbéyàwó lọ́tẹ̀ yìí lóòtọ́? Lateef bá BBC Yoruba sọ̀rọ̀
8 Bélú 2021
Wòlíì kan fún òṣèré tíátà ní miliọnu mẹ́fà náírà láti fi tọ́jú àìsàn rẹ̀
2 Bélú 2021
Ẹgbẹ́ TAMPAN ló mú kí ìjọba gbógun ti orísùn ọrọ̀ ajé mi - Yomi Fabiyi figbe ta
2 Bélú 2021
Kí ló mú Lizzy Anjorin ṣe àyẹ̀wò DNA ọmọ rẹ̀?
1 Bélú 2021
Òjò owó àti ẹbùn ń rọ fún Iyabo Ojo fún ayẹyẹ ọdún kan ikú ìyà rẹ
31 Ọ̀wàrà 2021
Òṣèré Tíátà ṣèèṣì yìnbọn lórí ìtàgé, arábìnrin kan ti forí la ikú, òmìí farapa
22 Ọ̀wàrà 2021
Mí ò ṣe sinimá 'Iku ni' láti tàbùkù ẹ̀sìn Islam - Olufunmi Bakare
18 Ọ̀wàrà 2021
Bimbo Oshin ṣàlàyé ọ̀rọ̀ ìkẹyìn tí ọkọ rẹ̀ sọ fun un kó tó kú
15 Ọ̀wàrà 2021
"Á fimú Odunlade Adekola dánrin tó bá kọ̀ láti ṣe àtúnṣe lórí títàbùkù ẹ̀sìn Islam nínú fíìmù rẹ̀"
15 Ọ̀wàrà 2021
A pinu láti sinmi díẹ̀ lẹ́yìn ìgbeyàwó ká tó bímọ àmọ́ ó yíwọ́ - Wumi Toriola
14 Ọ̀wàrà 2021
Odunlade, a fún ọ lọ́jọ́ méje, yọ sinimá tó ń fi ẹlẹ́hàá ṣe yẹ̀yẹ́ kúró lórí ayélujára - Ẹgbẹ́ THURIST
13 Ọ̀wàrà 2021
Ohun tí ojú mi rí rèé lọ́wọ́ àwọn amojúẹ̀rọ lásíkò yíya sinimá - Adunni Ade
10 Ọ̀wàrà 2021
2:57
Fídíò,
Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé Peter Fatomilola ni 'Papa Ajasco' àkọ́kọ́?
, Duration 2,57
9 Ọ̀wàrà 2021
Àwọn Òṣèré fíìmù Yorùbá tẹ́ ò ro tó tí jápaa lọ ìlú Òyìnbó rèé
8 Ọ̀wàrà 2021
Obìnrin tó bá ń gbé bùkátà kò ní ọkọ kódà kó wà nílé ọkọ - Kemi Afolabi
6 Ọ̀wàrà 2021
Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ nípa ikú ìyá rẹ̀, ó tún tú àṣírí kàbìtì nípa ìhùwàsí ara rẹ̀ táyé kò mọ̀
5 Ọ̀wàrà 2021
Ìṣájú
Page
25
nínú
38
1
22
23
24
25
26
27
28
38
Tókàn