BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Oyo
Orí àgbá ẹ̀tù láwọn èèyàn Ibarapa jókòó lé, wàhálà ń bọ̀ - OPC mẹ́ta tó gba ìdáǹdè
29 Òkùdu 2021
Mo dẹ́kun àdúrà gbígbà lẹ́yìn ikú Ajimobi - Florence aya olóògbé
28 Òkùdu 2021
Kìí ṣe iṣẹ́ bárà nìkan ni àwọn àkàndá lè ṣe jẹun, àìsí ìrànlọ́wọ́ ní kò jẹ́ kí ọ̀pọ̀ ṣe fújà
26 Òkùdu 2021
"A ń sàárò ọgbọ́n ìṣèjọba àti òṣèlú tí Sẹ́nétọ̀ Abiola Ajimobi ni nígbà ayé rẹ̀"
26 Òkùdu 2021
Àwọn agbébọn pa ìyàwò èèkàn olóṣèlú ní Ibadan, ọlọ́pàá ní adigunjalè ní wọ́n
26 Òkùdu 2021
Ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo àti àwọn ẹlẹ́sìn àbáláyé bẹ̀rẹ̀ àjọṣepọ̀ láti fí opin sí ìṣoro ètò aàbò
24 Òkùdu 2021
Èèmọ́! agbébọn jí Olóyè Tafa àti ìyàwó rẹ́ gbé nílu Ibadan
23 Òkùdu 2021
Àwọn lọ́balọ́ba nílẹ̀ Yoruba dalẹ̀ wa lórí àwọn ọmọ OPC mẹ́ta tí wọ́n tímólé láìṣẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ Iskilu Wakili - Ẹgbẹ́ OPC
23 Òkùdu 2021
6:22
Fídíò,
Kò sí ẹni tí mo fura sí lórí ikú ọkọ mi, àmọ́...- Adebisi aya Titus Ejanla tí wọ́n pa ní Ibadan
, Duration 6,22
23 Òkùdu 2021
Lẹ́yìn ìjà tò gbẹ̀mí èèyàn bíi mẹ́ta, Makinde sè ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ àlákòóso Amọtẹkun
22 Òkùdu 2021
Ẹ wo ohun tí a mọ̀ nípa bí agbébọn ṣe gbẹ̀mí sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀, Titus Badejo Ejanla ní ìlú Ibadan
20 Òkùdu 2021
Bìlísì míì wáyé n‘Ibadan, ọmọ ìṣọta kọlu OPC, ẹ̀mí bọ́
18 Òkùdu 2021
N5M ni a pàdánù lásìkò tí ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo lé wa kùró ní Sabo - Àwọn oníbárà
17 Òkùdu 2021
4:06
Fídíò,
Ṣé ìrìnàjò nínú ọkọ̀ Reluwé Ibadan-Lagos-Ogun tuntun bá aráàlù lára mu? Èsì rèé
, Duration 4,06
17 Òkùdu 2021
Rògbòdìyàn bẹ́ sílẹ̀ ní Iwo Road lọ́jọ́rùú, ẹ̀mí méjì bọ́, ọ̀pọ̀ farapa
16 Òkùdu 2021
Jàǹdùkú ti já ọdún eégún gbà n‘Ibadan, ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ti sùn - Ẹgbẹ́ ọlọ́dẹ pariwo
15 Òkùdu 2021
A ó sọ ibùdókọ̀ ojú irin ìlú Ibadan di gbàgede káràkátà láìpẹ́ - Ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo
15 Òkùdu 2021
Ìjọba Oyo ti bẹ̀rẹ̀ sí ní kó àwọn oníbárà kúrò láàrin ìgboro ìlú Ibadan
15 Òkùdu 2021
Kìí ṣe Gómìnà Seyi Makinde ló ṣètò ìwọ́de June 12 ní Ibadan kò sì bá wọn kópa - Taiwo Adisa
13 Òkùdu 2021
Àṣìgbé ọmọ wọ́ọ̀dù ni Seyi Makinde - Àgbààgbà PDP l‘Oyo ka ẹ̀sùn sí gómìnà l'ẹ́sẹ̀
11 Òkùdu 2021
6:38
Fídíò,
Ẹ kálọ sí Ogbomoso láti mọ́ àwọn ìbi pàtàkì tó jẹ́ ibùdó ìṣẹ̀ǹbáyé
, Duration 6,38
11 Òkùdu 2021
Àjọ EFCC mú àwọn afurasí aàdọ́ta tó ń lu jìbìtì lórí ayélujára ní Ibadan
9 Òkùdu 2021
Sunday Igboho ní òun ṣetán láti dira fáwọn ọ̀dọ́ Ibarapa fún ìpèsè ààbò aráàlú
9 Òkùdu 2021
Àwọn ọ̀dọ́ Igangan fárígá pé Seyi Makinde kò dúró gbọ́ èrò àwọn lásìkò àbẹ̀wò rẹ̀
9 Òkùdu 2021
Ìṣájú
Page
40
nínú
40
1
34
35
36
37
38
39
40