BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ifiyajẹni
Ìjọba Sokoto kéde òfin kóníléógbélé lẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn lórí bí ọlọ́pàá mú àwọn tó pa Deborah Samuel
14 Èbibi 2022
Wo ǹkan tó ń fa 'body odour' àti bí o ṣè lè ṣẹ́gun rẹ̀
14 Èbibi 2022
Okùnrin tó so àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ mọ́lẹ̀ bíi ewúrẹ́, tó sì nà wọ́n rí ẹ̀wọ̀n ogún ọdún he
25 Ìgbé 2022
Ki ló mú bàbá fí ìbínú fọ orí ọmọ rẹ̀ oṣù kan mọlẹ?
16 Ìgbé 2022
Seyi Makinde ti sọ Auxillary di nǹkan míì sígbòrò, ọlọ́pàá gbọdọ̀ mu - Olopoeyan
14 Ìgbé 2022
Ìwúlò Buhari fún Nàíjíríà tí tán, kò búrú tó bá kọ̀wé fi ipò sílẹ̀ - Ilana Omo Oodua
13 Ìgbé 2022
"Àwọn ọmọ ogun Russia fipá bá mi lòpọ̀, wọ́n tún pa ọkọ mi"
12 Ìgbé 2022
Ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ l‘Eko láàrin igun MC Oluomo àti ẹgbẹ́ awakọ̀ márúwá TOOAN
12 Ìgbé 2022
Mò ń bọ̀ nílé láìpẹ́, ìjọba yóò sanwó tó jẹ mí - Sunday Igboho
10 Ìgbé 2022
"Àwọ̀ ara àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó jóná nínú bọ́ọ́sì ń ṣí mọ́ wa lọ́wọ́ nígbà tà ń dóòlà ẹ̀mí wọn"
1 Ìgbé 2022
Ìbọn kò ran Tommy, làwọn afurasí ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn bá fi àdá ṣa pa - Óṣojúmikòró
30 Ẹrẹ̀nà 2022
Ajá pa ọmọ olówó rẹ̀ láàrin ọ̀sẹ̀ kan tí wọn rà á
27 Ẹrẹ̀nà 2022
Ológun ní kí aya mi bọ́ aṣọ kúrò lára, pa ọmọ mi mẹ́rin àtàwọn alátìlẹyìn mi - El Zakzaky
19 Ẹrẹ̀nà 2022
5:47
Fídíò,
‘Pure Water‘ ni wọ́n ní kí ọmọ mi mú wá, tí wọn fi tàn-án pa - Baba Roheem Bamimore
, Duration 5,47
18 Ẹrẹ̀nà 2022
Wọ́n tan bàbá 85 kúrò nílé, fọ́ igi mọ lórí, ju òkú rẹ̀ sétí odò l‘Ogun
17 Ẹrẹ̀nà 2022
Afurasí Fulani gé ọwọ́ Fijilańté méjèèjì ni Iwere Ile ni Ipinle Oyo
15 Ẹrẹ̀nà 2022
10:54
Fídíò,
Mo lo oṣù mẹ́ta ní àhámọ́ ológun àti DSS torí nọ́mbà Sunday Igboho tó wà lórí fóònù mi – Tula Oyo
, Duration 10,54
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Làásìgbò níbi ìpàdé PDP l‘Osun mú ẹ̀mí méjì lọ, ọ̀pọ̀ fara pa, dúkìá jóná
24 Èrèlè 2022
Ẹ wo bí ‘dókítà’ ṣe yọ àpò ẹyin ilé ọmọdébìnrin kan lásìkò iṣẹ́ abẹ́
11 Èrèlè 2022
6:44
Fídíò,
"N kò mọ ẹni tí ọkọ́ mi ṣẹ̀, tí wọn fi ṣa ní àdá, tó sì gba ibẹ̀ kú lẹ́yìn oṣù mẹ́sàn-án"
, Duration 6,44
7 Èrèlè 2022
Bí ìsìn alẹ́ onígbàgbọ́ ṣe ń wáyé fún ìsìnkú Timothy Adegoke, mọ̀lẹ́bí tẹ́wọ́ gba òkú rẹ̀
28 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Myanmar ṣekúpa èèyàn 40, wọ́n lu àwọn míì títí tí ẹ̀mí fi bọ́ lẹ́nu wọn
21 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ọmọ ogun méjì rí ẹ̀wọ̀n he lẹ́yìn tí wọ́n yìnbọn pa olùfẹ̀hónúhàn lọ́dún 2020
10 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ọ̀rọ̀ ìkẹyìn tí ọmọ mi, Sylvester Oromoni sọ fún wa nìyí nínú ìrọra kí ó tó kú, òní ni ọjọ́ ìbí rẹ̀!
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ìṣájú
Page
10
nínú
14
1
7
8
9
10
11
12
13
14
Tókàn