BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Ojú ewé to wà yìí,
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Eré ìdárayá
₦147m la rí kójọ fún ìwọ́de, a kò fẹ́ owó mọ́, ìwọ́de ti parí - Feminist Coalition
23 Ọ̀wàrà 2020
Àfikún owó epo, owó iná àti owó orí VAT ló jẹ́ ká fowó kún tàríìfù DSTV- Ọ̀gá MultiChoice
13 Ọ̀wàrà 2020
Mo sì ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́ lẹ́yìn tí Fury fẹ̀ṣẹ́ já iṣan ọwọ́ mi loṣù mẹ́jọ sẹ́yìn- Deontay Wilder
11 Ọ̀wàrà 2020
Olivier Giroud fi àràmọ̀ndà góòlù méjì ṣayẹyẹ ìfẹsẹ́wọnsẹ̀ ọgọ́rùn ún tó gbá fún France
8 Ọ̀wàrà 2020
Cavani dèrò Man United, Arsenal bínú ra Partey ní £45m, Walcott padà sí ẹsẹ àárọ̀
6 Ọ̀wàrà 2020
Ayé má níkà o! Tottenham ya aṣọ iyì mọ́ Manchester United lára nírọ̀lẹ́ ọ̀jọ́ ìsinmi
4 Ọ̀wàrà 2020
Dákúdájí Chelsea bínú já òrùlé Stamford Bridge lé Crystal Palace lórí
3 Ọ̀wàrà 2020
Nínú akànṣẹ́ mẹ́ta ọmọ Nàìjíríà tó dáńtọ́ lágbàáyé, Yorùbá méjì wà nínu wọn
27 Owewe 2020
Alámì ẹ̀yẹ Scrabble Paul Sodje àti ọ̀rẹ́ rẹ́ kú lásìkò tó fẹ́ lọ́ sanwó ìdóòlà ẹ̀mí àbúrò rẹ̀, tí afurasí darandaran jí gbé
10 Owewe 2020
Mo ṣetán láti fi ẹ̀ṣẹ́ dín dòdò ìyà fún Anthony Joshua- Efe Ajagba
3 Owewe 2020
Awo lọ? Messi ò lè dúró mọ́, aṣojú Manchester City ti balẹ̀ sí Barcelona láti dú ìná dúrà
1 Owewe 2020
Ronald Koeman di akọ́nimọ̀ọ́gbá Barcelona tuntun lẹ́yìn ìjàmbá Champions League
19 Ògún 2020
Àwọn afẹ̀hónúhàn bọ́ra sí ìhòhò lórí pápá lòdì sí sísọ eré bọ́ọ̀lù di jẹunjẹun
17 Ògún 2020
Wọ́n ti sún ọjọ́ ìjà Mike Tyson pẹ̀lú Roy Jones Jr síwájú
10 Ògún 2020
Lampard laná! Arsenal fa Chelsea ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ gba ife FA Cup
1 Ògún 2020
Ọmọ Nàìjíríà di agbábọ́ọ̀lù Áfíríkà tí iye owó tí wọ́n rà à ga jù nínú ìtàn!
31 Agẹmo 2020
5:33
Fídíò,
Mama Arsenal ṣeé débi èrè, ẹgbẹ́ kan ti fún màmá l'ẹ̀bùn owó
, Duration 5,33
23 Agẹmo 2020
Real Madrid gbadé ògo La Liga, Messi ní Barcelona ò lè ta pútú mọ́
17 Agẹmo 2020
Ó fipá bámi lòpọ̀, ó lù mí, ó tún gba gbogbo owó mi- Funke Oshonaike
14 Agẹmo 2020
Ayé le! Sheffield faṣọ iyì ya mọ́ Chelsea lára lọ́nà ìrìnàjò sí Champions League
11 Agẹmo 2020
Wo agbábọ́ọ̀lù Super Eagles Nàìjíríà àkọ́kọ́ tó lùgbàdì coronavirus
9 Agẹmo 2020
6:02
Fídíò,
Nàíjíríà já mi kulẹ̀ - Oladapo Adu
, Duration 6,02
8 Agẹmo 2020
West Ham fi omi àbùkù wẹ Chelsea láwọlé sùn, Arsenal yìnbọn pa Norwich
3 Agẹmo 2020
Ògbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù tẹníísìì Novak Djokovic ti lùgbàdì coronavirus
23 Òkùdu 2020
Ìṣájú
Page
17
nínú
22
1
14
15
16
17
18
19
20
21
22
Tókàn