BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Ondo
A ti wà nínú igbó láti ṣàwárí àwọn mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ikaramu Akoko - Amotekun Ondo
22 Ìgbé 2021
Ó dá wa lójú pé Eyitayo Jegede á borí nílé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn- Ondo PDP
21 Ìgbé 2021
Màálù 250 tasẹ̀ agẹ̀rẹ̀ wọ oko ní Ilaramọkin, ní ikọ̀ Amotekun bá sọ Màálù àti olówó rẹ sí gbaga
19 Ìgbé 2021
Ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ lórí ikú tó pa olùkọ́ fásitì Adekunle Ajasin tó kú sínú mọ́tò - Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ondo
8 Ìgbé 2021
"Nǹkan tó lé pa màálù 30 lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lé pa ènìyàn, ẹ̀yin àrá Ondo, ewu ńbẹ"
31 Ẹrẹ̀nà 2021
Akintoye sá lọ Amẹrika lásìkò ìjọba ológun, ó wá fẹ́ da Naijiria rú báyìí - Akeredolu
27 Ẹrẹ̀nà 2021
Sùkẹ̀! Ọ̀rọ̀ òṣèlú ni gbogbo ẹ tí Akeredolu ṣe tako ìdásílẹ̀ Oduduwa Nation - Banji Akintoye
26 Ẹrẹ̀nà 2021
7:23
Fídíò,
Gómìnà máa ń tẹ̀ lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan láti wa ojú iré ìjọba apapọ̀, àmọ́ ọmọ wa náà ṣì ni Akeredolu - Banji Akintoye
, Duration 7,23
26 Ẹrẹ̀nà 2021
Ìdìbò ọdún 2023 leè má wáyé bí ìjọba kò bá yanjú ìpèníjà ààbò - Akeredolu
24 Ẹrẹ̀nà 2021
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí márùn ún míràn lórí ikú ọmọ Fasoranti
17 Ẹrẹ̀nà 2021
Gómìnà Oyetola àti Akeredolu gba abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19, wọ́n ní kò séwu nípa rẹ̀
10 Ẹrẹ̀nà 2021
'Ọkọ̀ ńlá méjì ló kó àwọn Fulani wọ Ajowa Akoko ní Ondo, àmọ́ a ti jọ ń sọ̀rọ̀ pé ...'
7 Ẹrẹ̀nà 2021
Àwọn òṣìṣẹ́ Shoprite bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn ní Ibadan, Akure, Eko àtàwọn ìlú míràn
2 Ẹrẹ̀nà 2021
Owó Taxi ní ìpínlẹ̀ Ondo tí padà sí N50 látí N100 nítorí kò sí gbígba ''tíkẹ́ẹ̀tì'' NURTW mọ́
2 Ẹrẹ̀nà 2021
Ẹ wo èrò àwọn ènìyàn lórí bí Gòmìná Akeredolu ṣe fòfin de NURTW, RTEAN nípínlẹ̀ Ondo
2 Ẹrẹ̀nà 2021
Nítorí 'áfúsá', àwọn nọ́ọ̀sì bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì l'Ondo
1 Ẹrẹ̀nà 2021
Èèyàn méje móríbọ́ lẹ́yìn tí àwọn ajínigbé àtàwọn ọdẹ ìlú rọ òjò ìbọn fún ara wọn l'Ondo
28 Èrèlè 2021
6:54
Fídíò,
Láti 1978 tí Bàbá mi ti jẹ Oba Isinkan ni mo ti mọ̀ pé máà jẹ adelé- Margret Omonije
, Duration 6,54
28 Èrèlè 2021
Mo ṣèlèrí láti ṣa ipá mi fún ìpínlẹ̀ Ondo ní sáà kejì - Rotimi Akeredolu
24 Èrèlè 2021
Ọ̀pẹ́lọpẹ́ àwọn tí kò dá a dá àwa onílé nìkan, kò bá ti ràn mọ́ ilé epo - Ará àdúgbò Oyemekun
24 Èrèlè 2021
Ọlọ́pàá ò pe àwọn olóyè Ifon nítorí màálù tó kú, a fẹ́ gbọ́ tẹnu wọn lásán ni - Agbẹnusọ Ọlọ́pàá
22 Èrèlè 2021
Àwa ìpínlẹ̀ fúnra wa ló yẹ ká máa ṣàkóso inú igbó wa - Àfẹnukò àwọn gómìnà àti àwọn Ọba Yorùbá
21 Èrèlè 2021
Ìrọ́ ní ò, a o fí ìgbà kankan fí Olupelumi Fagboyegun, Ìbátan Akeredolu sí ẹ̀wọ̀n- Iléẹ́jọ́ ìpínlẹ̀ Ondo
17 Èrèlè 2021
Ọbalayé tó kéré jùlọ nílẹ̀ Yorùbá, Oloyede Akinghare gbadé
17 Èrèlè 2021
Ìṣájú
Page
26
nínú
37
1
23
24
25
26
27
28
29
37
Tókàn