BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Ondo
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo sọ̀rọ̀ lórí ìdájọ́ tó dá Sotitobire láre pé kò jí ọmọ kankan gbé
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Wọ́n yọ ẹ̀yà ara màmá wa tí wọn pa ní ṣọ́ọ́ṣì Deeper lọ - Ẹbí pariwo
30 Bélú 2021
Ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí àwọn olólùfẹ́ yìí tí wọ́n bá okú wọn ní ilé ìgbọ̀nsẹ̀ wọn
28 Bélú 2021
Ọmọ tuntun tí wọ́n bá lórí pẹpẹ ṣọ́ọ́ṣì gba orúkọ tuntun
27 Bélú 2021
Pásítọ̀ onísọjí tó fí ipá bá olóyún oṣù mẹ́jọ sùn ní Ondo, ohun tí a mọ̀ rèé
19 Bélú 2021
'Kò lòdì sí ofin láti yàn mọ̀lẹ́bí sí ipò, àmọ́ ṣé ọ̀mọ̀ Akeredolu kójú'òsùwọ̀n ìpò tí bàbá rẹ̀ yàn án sí?' - Onímọ̀ òṣèlú
17 Bélú 2021
Èèmọ̀! Ọmọbìnrin kan bá ara èèyàn nínú fìríìjì ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀
16 Bélú 2021
Àwọn ajínigbé pa èèyàn méjì l’Akure, ẹnìkan móríbọ́, ẹnìkan ṣì wà ní ìkáwọ́ wọn
16 Bélú 2021
Ọwọ́ ikọ̀ Amotekun tẹ afurasí ajínigbé tó n múra bíi wèrè ní gáréèjì Akure
13 Bélú 2021
Ọ̀pọ̀ arìnrìnàjò jóná, àwọn mìí tún farapa nínú ìjàmbá ọkọ̀ ní Okitipupa
13 Bélú 2021
Akeredolu kéde òfin kónlé-ó-gbélé ní Igbara-Oke torí rògbòdìyàn lórí ìbò kánsílọ̀
12 Bélú 2021
Ilé ẹjọ́ gba béèlì àwọn òṣìṣẹ́ ilé ọmọ aláìlóbìí méjì tí wọ́n lo ta ọmọ obìnrin alárùn ọpọlọ
11 Bélú 2021
"Ọmọ kan ṣoṣo tó bí fún mi ni wọ́n gún lọ́dún mẹ̀ta sẹ̀yìn kí wọ́n tó gún òun náà pa báyìí"
10 Bélú 2021
4:31
Fídíò,
'Ẹ yé tan ara yín, èmi mo ni aṣọ 120 yard tó jábọ́ lát'ọ̀run táwọn ará Ondo ń ya mọ́ ara wọn lọ́wọ́'
, Duration 4,31
10 Bélú 2021
'Bí ẹni gbọ́ ikú bàbá rẹ̀ ló rí lásìkò tí a gbọ́ pé Akeredolu gbé owó ilé ẹ̀kọ́ wa sí ₦2.245m'
8 Bélú 2021
Ọ́dọ́kùnrin 18 láti òkè ọya pẹ̀lú ohun ìjà olóró dojú ìjà kọ Àmọ̀tẹ́kùn l'Ondo
6 Bélú 2021
Ọwọ́ Amotekun tẹ ọ̀dọ́ 18 tó rìn gbéregbère wọ Akure láti òkè ọya
3 Bélú 2021
Olusegun Mimiko àti ẹgbẹ́ rẹ̀, ZLP darapọ̀ mọ́ PDP
29 Ọ̀wàrà 2021
Ajínigbé jí ọmọ ìyá méjì gbè lákàtà ìyá wọn nílùú Akure
23 Ọ̀wàrà 2021
Ta ni yóò jẹ Ọba dá ìjà sílẹ̀, òjò làásìgbò ń sú ni Iralepo Isinkan nílùú Akure
23 Ọ̀wàrà 2021
Godwin ṣá bàbá rẹ̀ ládá pa nítorí orí adìyẹ, Ó ní...
15 Ọ̀wàrà 2021
Agbébọn yìnbọn pa akẹ́gbẹ́ rẹ́ lásìkò ìjínígbé tí wọ́n kójú Àmọ̀tẹ́kùn
8 Ọ̀wàrà 2021
Òjò alágbára rọ̀ ní Ikare-Akoko, ilé àádọ́jọ bá a lọ, èèyàn kan tún kú
4 Ọ̀wàrà 2021
Nǹkan ṣẹlẹ̀ l'Abuja, Ondo àti Eko lọ́jọ́ Òmìnira
1 Ọ̀wàrà 2021
Ìṣájú
Page
22
nínú
37
1
19
20
21
22
23
24
25
37
Tókàn