Ẹlẹ́mí èṣù làwọn ayálégbé míràn, àfi kí ìjọ̀ba yọwọ́ lọ́rọ́ onílé àti ayálégbé ní Nàìjíríà – Isaac Fayose

Àkọlé fídíò, Ẹlẹ́mí èṣù làwọn ayálégbé ní Abuja, àfi kí ìjọ̀ba yọwọ́ lọ́rọ́ onílé àti ayálégbé ní Nàìjíríà – Isaac Fayose
Ẹlẹ́mí èṣù làwọn ayálégbé míràn, àfi kí ìjọ̀ba yọwọ́ lọ́rọ́ onílé àti ayálégbé ní Nàìjíríà – Isaac Fayose
Published

Ninu eto 'Nibo laye kọju si?' tọsẹ yii, eekan kan lawujọ, Isaac Fayose ṣalaye ọrọ nipa ọrọ larinlọọdu ati ayalegbe. O ni ko si ohun to yẹ ko kan ijọba nipa inọja laarin larinlọọdu ati ayalegbe nitoripe ontaja ati onraja ni.

Nigba to n sọrọ nipa ọrọ faakaja laarin oun atawọn ayalegbe rẹ kan, o ni ẹlẹmi eṣu lawọn ayalegbe miran.

Ni abala keji a tun mu ọrọ ajọṣepọ laarin iya ọkọ ati iyawo wa fun yin.

Ẹ wa data ra, ẹ wa nnkan fidi le ki ẹ fun oju lounjẹ