Wo àwòrán bí àwọn Kristẹni ṣe ṣe àyájọ́ ọjọ́ Ẹtì rere

Aworan ọkunrin kan to mura bi Jesu Kristi
Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọjọ Ẹti rere ni ọjọ Ẹti saaju ọjọ ajinde .

Ọdọọdun ni ayajọ yii ma n waye lati fi ṣe iranti Jesu Kristi, paapa ijinde Jesu Kristi.

Saaju, awọn Kristẹni ma n ṣe ayajọ Ọjọ Ẹti rere pẹlu ibanujẹ ọkan, ti wọn si ma n fi ọjọ naa gba awẹ.

Ni ọdun 2025 yii, Ọjọ Ẹti ree bọ si ọjọ Kejidinlogun oṣu kẹrin.

Ẹ fun oju yii lounjẹ pẹlu awọn aworan ayajọ Ọjọ Ẹti kaakiri agbaye ni ọdun 2025.

Ọkunrin kan lati Philippines.
Lati orilẹede India
Ni Philippines.
Aworan
Aworan lati Australia.
Aworan lati Philippines
Ọkunrin kan ti wọn kan mọ agbelubu
Aworan lati Philippines
Aworan lati Philippines