Eid celebrations in Africa: Báyìí láwọn mùsùlùmí ti ṣe ọdun ìtúnu ààwẹ̀ káàkiri ilẹ̀ Afirika lásìkò covid-19 yìí

Awọn musulumi ree ni mọṣalaaṣi lorilẹede Tanzania
Published

Awọn musulumi ṣe ayẹyẹ ọdun itunu awẹ, Eid al-Fitr kaakiri ilẹ Afirika, eyi tii ṣe ipari oṣu Ramada.

Bayii lawọn musulumi ṣe ki rawọn ni Nairobi...
Àkọlé àwòrán, Bayii lawọn musulumi ṣe ki rawọn ni Nairobi...
Bayii lawọn musulumi ṣe ki ara wọn ni Nairobi, Kenya, May 24, 2020.
Awọn musulumi takete si ara wọn nigba ti wọn kirun ọdun itunu awẹ
Bayii ni wọn ṣe ki olootu ijọba ilẹ Tanzania, Kaasim Majaaliwa ku ọdun
Awọn ọmọde yii n bọ lati irun Eid Fitr ni Nasarawa
Àkọlé àwòrán, Ei
Ọmọ musulumi yii n ṣe aluwala ni mọṣalaaṣi Eid al-Fitr ni Kara Ibafo nipinlẹ Ogun
Awọn musulumi n kirun Eid Fitr ni Nasarawa
Awọn musulumi takete si ara wọn nibi irun Eid al-Fitr ni Kara Ibafo ni ipinlẹ Ogun
Bayii lawọn musulumi ṣe kirun Eid al-Fitr ni Kara Ibafo ni ipinlẹ Ogun
Awọn musulumi ree olu ilu Sudan, Khartoum
Ọkunrin yii lo ibomu kirun ni Khartoum
Presentational white space
Pẹlu ibomu lawọn musulumi fi kirun ninu ọdun itunu awẹ ni Dakar, lorilẹede Senegal
Eti okun ni ọkunrin yii ti kirun niluu Dakar, ni Senegal
Mọṣalaaṣi kan ree lolu ilu Tunisia, Tunis.
Mọṣalaaṣi ilu Cairo, Egypt ree lọjọ ọdun itunu awẹ

All pictures subject to copyright