Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Ilu Igbokoda ti o safihan omi nla ati igi ọpẹ
  • Oriyomi Hamzat wọ asọ toke tilẹ alawọ buluu, o si pa ọwọ mẹ mejeeji papọ siwaju
  • Bimpe Akintunde (Wasila Coded)
  • Bashiru Awawu, agbábọ́ọ̀lù Flamigoes wọ asọ ere bọọlu fawọn obinrin, o si fa fila rẹ bori
  • Toyosi Adesanya to wọ asọ Adirẹ kaba olomi aro, gbe ọmọ tuntun lọwọ rẹ mejeeji, ati ọkọ rẹ n wo oju ọmọ tuntun naa
  • Temilolu Nurudeen Ashamu wọ asọ toke tilẹ ati agbada alawọ buluu, o si de fila to ba mu. O duro, o ka ọwọ mejeeji papọ siwaju rẹ
  • Francis Olusegun wọ asọ oye bii akẹkọjade tii se alawọ omi aro, o wọ shaati funfun sabẹ rẹ, o si de tai pupa sọrun. O tun de fila asọ ikẹkọjade naa
  • Awọn ọmọ ẹgbẹ akọrin lọkunrin lobinrin, awọn ọkunrin wọ toke tilẹ alawọ waini nigba ti awọn obinrin wọ kaba alawọ pupa
  • Obinrin kan to n sare lori papa wọ asọ alawọ ewe ati funfun
  • Ọkunrin to wọ asọ toketilẹ alawọ buluu ati fila awọn eeyan loke Ọya
  • Iyawo Oyedokun wọ asọ leesi funfun, o we gele pọpu
  • Olusegun Obasanjo wọ asọ toketilẹ alawọ funfun ati fila pọpu, o mu ẹrọ amohunbugbẹmu lọwọ alaafia rẹ

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ