Nigeria vs Argentina: Kìí dùn kópè, ó tún dìgbà kan ná

Published

Ìfẹsẹ́wọnsẹ̀ náà f'ọwọ kàn òpó olólùfẹ́ Super Eagles l'ẹ́mìí

Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Ẹkùn ló parí ọrọ ifẹsẹwọnsẹ náà fún arákùnrin yí ní ìlú Èkó
Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Àwọn alatilẹyin Super Eagles orílèèdè Naijirià káwó lórí bí Argentina ṣe jẹ góòlù kejì
Àwòrán alatilẹyin Argentina
Àkọlé àwòrán, Níbi tí ẹlẹkun tí n sunkún
Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Kelechi Anyikude ro dédé kàn dudu ṣáájú ifẹsẹwọnsẹ Naijirià àti Argentina
Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Alawada Oluwakoponeski fi àwòrán yí níbi tó tí dákú ṣòwò lójú òpó Twitter.
Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ agbaboolu AS Roma fí ọrọ ìkíni ranṣẹ sójú òpó Twitter wọn sì ìkọ Super Eagles
Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Lorílè-èdè Kenya,àwọn ọmọ ilẹ áfíríkà gbe lẹyìn Super Eagles sugbọn ẹpa kòo boro mọ
Àwòrán alatilẹyin Super Eagles
Àkọlé àwòrán, Awakọ bàálù tí yóò gbé wọn padà wálé tí wà ní ṣepe